
Ohun ti a gbo bayii ni pe odomode sheu naa fee segbeyawo alarinrin lorile-ede Amerika lojo kefa, osu kin in ni odun to n bo.

Latigba ti iroyin igbeyawo sheu yii ti kan awon eeyan kan lara ninu won ti n dun pe oun tawon fe ko sele lati ojo yii wa ni sheu fee se yii.
Awa naa sadura fun sheu wa pe ojo ayo lojo naa yoo je, bee niyawo yoo bisu,yoo biwale, ile alayo ko ni i daru.
No comments:
Post a Comment