Leyin aseyori tawon rekoodu e akoko ti se, gbajugbaja aafa oniwaasi nni,Maolana Sheik Ishaq Zubai Al-Bayanny ti gbogbo aye mo si Won-se-ni-gan-pa yoo tun gbe rekoodu itan- igbesi aye ilu mo on ka osere fuji nni, Alaaji Wasiu Alabi Ajibola Pasuma jade. Rekoodu naa to ti yoo jade lose to n bo nileese Sarolaj Music yoo gbe jade, oun naa ni yoo pin in fun gbogbo awon to n ta rekoodu lorile-ede yii.Rekoodu tuntun yii ni Won-se-ni-gan-pa ti so itan igbesi- aye Pasuma, bi won se bi i,bo se kekere,bo se kawee, bo se dedii orin,awon isoro to koju e ati bo se di gbajumo nidii orin.
Gbogbo ibi ti won ti n ta rekoodu lawon eeyan yoo ti ri itan igbesi aye Pasuma yii ra. Gbogbo awon to ba fee mo ojulowo itan Pasuma lo gbodo ni rekoodu yii lowo

No comments:
Post a Comment