Igbimo to sakoso ibo abele egbe APC nipinle Eko ti so pe awon ti sun ojo idibo abele ipo gomina egbe naa sojo mi-in. Won ni ibo awurudu gba a leyi ti won koko di yii.
Lasiko to n soro nipa igbese ti won gbe yii, alaga igbinmo yii ni awon yoo kede ojo tibo mi-in yoo waye. O te siwaju ninu oro e pe awon sese gba oruko awon asoju oludije mejeeji naa, iyen Ambode ati Sanwo-Olu.
No comments:
Post a Comment