IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday, 2 October 2018

AWON ARA OSHODI DOJU TI AMBODE, IBO REPETE NI WON DI FUN SANWO-OLU

Nnkan loro awon ara awon omo egbe APC Oshodi yii o, ohun ti won se fun Ambode ninu ibo abele gomina ipinle Eko to waye loni-in ko dara rara. Ibo repete ni won di fun Sanwo-Olu, won lawon ko fe Ambode mo nipo gomina Eko

No comments:

Post a Comment

Adbox