IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday, 28 September 2018

HAPI BATIDE, ALAAJA AMINAT, IGBA ODUN, ISEJU AAYA NI

Gbogbo wa pata nileese Ojutole la ki eeyan wa daadaa, Alaaja Aminat Kazeem,
ku oriire ojoobi won to waye loni-in. Adura wa ni pe ki won sopo odun laye ninu owo, ola ati alaafia ara.

E je ka se  Gbosa meta fomo olojoobi 

No comments:

Post a Comment

Adbox