Erin nla ti wo, ajanaku nla ti sun bii oke laarin awon musulumi orile-ede yii, aafaa oniwaasi nla, Kaliifa Sheik Muhammad Tajudeen Abdul Azeez Olohungbolo jade laye laaro oni.
Okan lara awon aafaa nla, ti won sise adinni loju mejeeji ni baba yii, ilu Abeokuta ni won fi sebugbe. Ki Olorun forji ji baba to lo, ko fi alujanna onidera tawon lore.

No comments:
Post a Comment