IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Thursday, 1 February 2018

Won sayeye ojoobi fun Lateef Oladimeji, senken ninu okunrin naa n dun

Taofik Afolabi



Ohun to daju saka ni pe lara ojo ti gbajumo osere tiata Yoruba nni, Lateef Oladimeji, ko ni i gbagbe boro laye e lonii ti i se ojo kin- in- ni, osu keji, odun 2018, ti osere tawon eeyan feran daadaa naa sayeye ojoobi e.

Sugbon kinni kan to je ki ayeye ojoobi naa dun mo on ninu ni pe awon ololufe e kan seye nla ti ko ro lokan fun un, eyi tawon oloyinbo n pe ni sopuraisi batide paati.

Ju gbogbo e lo, oni ye Oladimeji, ki Eledua je ki ola dun fun un ju oni lo. Igba odun,odun kan ni o   

No comments:

Post a Comment

Adbox