IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 4 February 2018

Remmy-Shita Bey, Adebayo omo Iya Aje, lo sojoobi,e je ka ki gomina ANTP tele ku oriire

Oni ni Alaaji Remmy Shita-Bey ti gbogbo aye mo si Adebayo Omo Iya Aje le ojo kan si i looke eepe, gbogbo wa pata nileese Iroyin Ojutole-Toko la ki gomina atijo fun  egbe osere 'ANTP' ku oriire.

A ba eeyan wa pataki dupe lowo Olorun ti ojo onii soju won, adura wa ni pe ki Alaaji Remmy ti wa pe bii mope se n pe, ko dagbadagba, ko se opo odun laye ninu ola,ola ati alaafia ara ati arisiiki to ka mama.
Igba odun,odun kan ni sir
.  

No comments:

Post a Comment

Adbox