
Gege bi a se gbo, gbogbo eto bi irin-ajo naa yoo se lo daadaa ni puromota Iya Kaola, S.G Entertainment Music and Cultural Promotion ti se sile, ti gbajumo akorin esin yii naa si ti n mura sile lati oko leti wo ilu oyinbo.
Awon ilu bii: Dalas, Texas, Maryland, Los Angeles, Oakland, Houston, Chicago, Miami ati Newyork.
Lasiko to n ba wa soro, Iya Kaola salaye fun wa pe oun yoo lo asiko naa lati forin aladun da awon ololufe oun ti won ti reti oun lati ojo pipe laraya. Bakan naa lo so pe oun yoo tun korin ni lorile-ede Canada
No comments:
Post a Comment