IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday, 6 February 2018

Owo EFCC TE AWON OMO YAHOO ATI BABALAWO WON NI SAGAMU

Image may contain: 2 people, people standing, car and foodImage may contain: 8 people, people standing, shoes and beardOwo ajo ileese to n ri si sise owo ilu basubasu  'EFCC', eka tiluu Eko ti te awon eeyan kan ti won pe ni ojibiti. Esun ti won fi kan awon meeedogun naa ni pe won fogbon gba owo lowo awon eeyan, fifi fogbon gbowo lowo awon obinrin pe awon fee fe won.
Awon eeyan towo te ohun: Adeyemi Tiwatope, omo ogun odun; Odeyemi Olawale, omo ogun odun; Nike Afolabi Olaiya, omo ogun odun; Awe Abimbola Ireti, omo odun metalelogun; Yusuf Aliu Oluwafemi, omo ogun odun; Osidipe Olatunbosun, omo odun merinlelogun; Tosin Adesanya, omo odun mokandinlogun ati Adeyinka Bello,omo odun metalogun,

 Aliu Lukman, omo odun mejinlogun; Damilola Fatona, omo ogun odun; Shonubi Adetola, omo odun mejidinlogunn, Adewale Babatunde, omo odun metalogun, Afolabi Lekan, omo odun mokandinlogun; Awe Ayodele, omo odun merinlelogun ati Adeyemi Gbadebo, omo odun mokanlogun.  Adugbo kan ti won n pe ni Shotubo ati Awoluwo niluu Sagamu, nipinle Ogun lowo ti te awon eeyan naa.

Image may contain: 3 people, people sitting

 Leyin iwadii awon olopaa otelemuye lowo te awon eeyan. Aye alakata ati igbe aye awon olowo tawon eeyan yiin gbe lo je ki won funra si won. Awon ohun ti won ba lowo won ni:ero komputa alagbeka, foonu olowo iyebiye, oko ayokele olowo nla mefa, oogun abenu gongo, atawon siimu foonu repete. Bakan naa lowo ti te okunrin babalawo kan toruko e n je Adesanya Olaoluwa ti won lo soogun fawon onijibiti yii. 
 

No comments:

Post a Comment

Adbox