IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday, 6 February 2018

O n bo lona o, fidio Gigo latowo gbajumo olorin emi nni, Deborah Semande Ochaba

Gbogbo eto ti n lo lowo lori fidio Gigo ti gbajumo akorin emi nni, Deborah Semande Ochaba, fee gbe jade. Awo naa ti ilu mo on ka produsa awon olorin, Sola Abbey ti won n pe ni SBlair po po ti ileese Arems yoo gbe jade ni won ti n wo kaakiri ori telifisan bayii, tise si ti n lo lowo lori e bayii.

Lasiko to n ba wa soro, Deborah, tawon ololufe e mo si Gigo so pe ko ni i pe, ko ni i jina ti fidio naa yoo di ohun tawon eeyan yoo maa wo ninu ile won.  

No comments:

Post a Comment

Adbox