IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday, 23 February 2018

Ope o, Olaide, omo Yinka Quadri, bimo okunrin



Taofik Afolabi

Inu idunnu ati ayo nla agba-oje osere tiata Yoruba nni, Alaaji Abdulganiyu Yinka Quadri, wa bayii, okan ninu awon omo e, Olaide, lo bimo okunrin.

Lasiko to n kede ohun ayo to sele si i yii, Agbakin ilu Oro, ni 'Mo dupe lowo Olorun fun ohun rere to se ninu ebi mi, omo mi Olaide lo bimo okunrin lantilanti'.

Awa naa ba a ba a dupe lowo Olorun fun oore ayo to sele sidile e yii.  

No comments:

Post a Comment

Adbox