IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday, 23 February 2018

Omo Mr. Somebody ree o, Oluomo Texas, to n se bebe l'Amerika

Lojokojo ti won ba n daruko awon omo Yoruba ti won n gbe oruko orile-ede yii ga niluu oyinbo, ohun to daju saka ni pe won yoo daruko Oloye Yinka Rythmz, ti gbogbo aye mo si Omo Mr.Somebody.

Yato si pe okunrin naa forin aladun gbe wa ga loke-okun, dokita alabere ni, bee lo tun joye Oluomo ati Atolase gbogbo ilu Texas. Oke aimoye ami-eye lokunrin naa ti gba, bee lo ti gbe
opolopo orin jade.   

No comments:

Post a Comment

Adbox