IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday, 23 February 2018

Ikunle abiyamo o: Tirela Dangote pa baba atomo e n'Ijebu-Igbo

Beeyan jori ahun, yoo saanu ikunle abiyamo to ba ri bi tirela ileese Dangote se pa okunrin kan atomo e, niluu Ijebu-Igbo, nipinle Ogun lasiko ti baba naa n mu omo e yii lo sileewe.

Gege bi a se gbo, se ni tirela yii loo ya ba awon eeyan naa, to si te won pa lojue-ese. Bi okunrin hausa to wa oko nla yii se ri i pe  ohun ti daran lo sa lo, awon olopaa ni won pale mo oku mejeeji naa, ti won gbe won lo si ile iwosan ijoba to wa niluu Ijebu-Igbo 

No comments:

Post a Comment

Adbox