IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 7 February 2018

Oni ni won yoo sinkuu Sola Durodola, purodusa awon elere ori itage

Oni, Wesde, ni won yoo sinkuu okan ninu gbajumo purodusa awon elere ori itage, to tun je adari fiimu, Sola Durodola, tawon eeyan mo si Oronro to ku laaro ojo Aje, Monde, ojo kefa, osu kin-in- ni, odun yii, leyin aisan raipe to se e. 

Itekuu to wa niAtan, nipinle Eko ni won yoo sin okunrin naa si. Ojutole naa ba gbogbo awon ebi e, atawon elere ori itage daro eni won to lo yii, ki Olorun te e safefe ire. 

No comments:

Post a Comment

Adbox