IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday, 6 February 2018

Oni lojoobi Oloye Timothy Agboola, e je ka ki Baba Oloye Repete ku oriire

A ba agba-oje sorosoro ori redio ati telifisan nni, Oloye Timothy Agboola, ti gbogbo aye mo si  Erekenisoobu dupe lowo Olorun pe won tun le odun kan si i loke eepe. Gbogbo wa pata la ba Baba Oloye Repete yo ayo ojoobi won yii.

Adura wa fun omo olojoobi ni pe ki won pe laye, ki won dagbadagba, ki oore repete wole to won wa, bo ti wu ke e pe laye to, e o ni i mo saare omo. Igba odun, odu

kan ni fun baba daadaa 

No comments:

Post a Comment

Adbox