IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 14 February 2018

Oni lojoobi Foluke Daramola-Salako, e je ka ba Ibadi-aran sayeye

Gbogbo aye pata ni won ba gbajumo osere tiata Yoruba nni, Foluke Daramola Salako, yayo ayeye ojoobi e to n lo lowo bayii. Oni ni losere  nla naa pe eni ogoji odun laye. Bile ti mo lawon ololufe e ti n ki i ku oriire  ayeye ojoobi naa.



No comments:

Post a Comment

Adbox