Gbogbo wa pata nileese Ojutole la ba Alhaja Abimbola Haroon, ti gbogbo aye mosi Iya Cairo, dupe lowo Olorun fun ayeye ojoobi e to waye lonii. Adura wa ni pe ko se opolopo odun laye ninu ola ati alaafia ara. A ba o dupe omo olojoobi.
No comments:
Post a Comment