
Laarin awon eeyan dudu atawon oyinbo alafo funfun ni won ti mo okunrin yii gbe ojulowo omo Yoruba to n lo imo t'Olorun fun un nipase orin to n ko so Naijiria di orile-ede pataki laarin awon oyinbo lokunrin yii.
Beeyan ba ri Beta Man nibi to ti n korin, eni bee yoo kan saara si ise opolo, gbogbo irinse orin pata losere nla yii mo on lo. Lara awon rekoodu to ti gbe jade ni 'Dide si iranlowo mi,Omo tuntun, bee lo ti gba polopo ami-eye nidii ise to yan laayo.
Oluwasegun ree, ojulowo omo Yoruba to n gbe oruko wa ga loke-okun ni.
No comments:
Post a Comment