IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday, 23 February 2018

Ola ni Obi Rere yoo se ikomo omo e,Saheed Osupa ni yoo korin nibe

Taofik Afolabi

Ola ti i se ojo ketalelogun, osu keji, odun yii ni gbajumo olorin islam nni, Alaaja Aminat Ajao Abubakar tawon eeyan mo si Obi Rere ati oko e, Alaaji Ganiyu Abubakar to ni ileese Kayus Motors yoo sayeye ikomo omo tuntun ti won bi. Ile igbafe 'Atlantic Hotel' to wa ni garaaji Offa, niluu  Ilorin, ipinle Kwara layeye naa yoo ti waye.

Gbajugbaja olorin fuji nni, Alaaji Saheed Osupa Akorede ni yoo korin nibi ayeye yii. Gbogbo awon olorin islam ni won reti nibi ayeye yii.

No comments:

Post a Comment

Adbox