IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday, 23 February 2018

Anjola Bravo ree o, oba orin juju ni Ireland niyen

Taofik Afolabi

Ti won ba n daruko awon olorin ti won se gudugudu meje ati yaaya mefa loke-okun, o daju saka pe won yoo daruko Anjola Leo Bravo si i. Okan ninu awon to n lo ebun orin ti Olorun fun un gbe ogo Yoruba ga lorile-ede Ireland losere yii.

Opolopo rekoodu ni Bravo ti gbe jade, bee lo ti gba ami-eye ti ko lo n ka. Ni nnkan bii odun meji seyin ni gbogbo awon omo orile-ede yii, ti won wa lorile-ede Ireland fi osere to rewa daadaa yii je oba orin juju, loju gbogbo awon dudu ati funfun ni won fi jawe oye le e lori,ti won fun un lade oba, ti won si fun un nirukere oye.

Anjola ree, ojulowo omo Yoruba to n gbe oruko orile-ede yii ga loke-okun ni
.  

No comments:

Post a Comment

Adbox