IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 11 February 2018

Oba orin juju ni Ireland, Anjola Bravo, fee gbe fidio 'Medley Gratitude' jade

Iroyin ayo ree fun gbogbo awon ololufe orin juju gidi pe gbajumo akorin juju nni, to tun je oba orin juju lorile-ede Ireland, King Anjola Leo Bravo, ti pari ise lori fidio orin kan to pe ni 'Medley Gratitude'. Fidio yii to ti wa lori ero ayelujara lawon ololufe orin gidi yoo gbadun nile  won to ba ti jade.

Lasiko to n ba wa soro, Anjola
so pe gbogbo awon ololufe oun ni won mo pe oun ki i gbe orin tabi fido ti ko muna doko jade. O ni bi won se gbadun oun ninu awon eyi toun ti se jade tele, bee gele ni won yoo tun ri idan tuntun latowo oun ninu eyi to n bo lona yii.

No comments:

Post a Comment

Adbox