IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday, 13 February 2018

Ha, Agba-oje osere tiata Yoruba, Joke Muyiwa, omo e ati iyawo omo e nijamba moto

Taofik Afolabi

Olorun lo ko gbajumo osere tiata Yoruba nni, Joke Muyiwa, omo e ati iyawo omo e, yo ninu ijamba moto to sele si won lojo Aiku, Sannde to koja yii.  Moto e toruko e n je 'Volkswagon Bora' losere nla yii fi nijamba moto lojo yii.

Gbara ti isele yii sele ni mama naa gbe e sori ero ayelujara pe kawon eeyan ba oun dupe lowo Olorun pelu bi oun ko se pare sinu ijamba oko yi.   

Awa naa ba won dupe lowo Olorun pe ijamba naa ko gba emi won, Olorun yoo fofo remi-in lori oko won to baje yii.

No comments:

Post a Comment

Adbox