IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday, 16 February 2018

O ma se o, Iya oko Rukayat Gawat olorin islam ti ku o

Taofik Afolabi

Asiko yii ki i se asiko kan gidi fun gbajumo akorin islam nni, Rukayat Aduke Gawat, aaro oni losere naa padanu iya-oko e.

Ninu oro osere naa lo ti tufo mama naa bayii pe 'Ki Olorun wa pelu yin, iya mi daadaa, won ku laaaro yii, Olorun tobi loba.

No comments:

Post a Comment

Adbox