IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 7 February 2018

Ijebu Onitiata ti loo jaye ori e ni Germany

Bi e se n ka iroyin yii, orile-ede Germany losere apanilerin-in nni, Tayo Amokade, tawon eeyan mo si Ijebu wa bayii,nibi to ti n jaye ori e.

Ni nnkan bii ose kan seyin losere yii bale siluu Germany nibi to ti n jaye ori e, tawon to loo ba nibe se toju e daadaa.

Awa naa ba Ijebu dupe lowo Olorun pe o gbe awada re de ilu Jamani.

No comments:

Post a Comment

Adbox