IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday, 17 February 2018

Gbogbo aye sedaro Ojogbon Akinwumi Isola

Iroyin to gba igboro ni kutu owuro ojo oni, ni pe, gbajumo Ojogbon onkowe nni, Akinwumi Isola ti jade laye. Gbara tiroyin iku naa kan awon eeyan lara ni kaluku ti n sedaro ojogbon to lo naa.

Díẹ̀ lára àwọn ìwé tí Olóògbé Akinwumi Isola kọ nìyí; Ẹfunsetan Aniwura, ó lè kú, koseegbe, Afaimo, abẹ ààbò, olú ọmọ, Akintoye, Tinubu, ogun ọmọdé, òrìṣà tí on gùn àwọn onkowe, one man square, spirit of Lagos ati bee bee lo.
 

Eni odun merinlelogorin (84) ni gbajumo omo Yoruba yii ko too jade laye laaro kutu oni ojo 
Abameta. Ekunrere gbogbo ohun to sele pata le o maa ka laipe.
1

No comments:

Post a Comment

Adbox