
Ayeye nla ohun yoo waye ni gbongan 'Klasik Arena Hotel', to wa ni adugbo Benefactor, ni AIT Road, Kollingon Bus-stop, Alagbado. Irawo ati agba-oje osere fuji nni, Aare Sir Shina Peters Akanni tawon tun mo si Ogolorinwa tabi Aroworeyin ni yoo forin fuji aladun da awon eeyan lara ya lojo yii.
Ninu oro omo olojoobi lo ti so fun wa pe oun fee lo ojo yii lati fi dupe lowo Olorun fun bo se pa oun mo lati inu oyun dakoko toun wa yii. Olori waa ro gbogbo awon ololufe e lati waa fi ojo naa ye oun si.
Fun alaye lekunrere, e pe Oloye Abiodun Adeoye tawon eeyan mo si Afefe Oro sori nomba yii:08034208134 tabi Alaaja Abimbola Owodunni sori: 08023883517
No comments:
Post a Comment