
Eto yii ti ogbontarigi pedepede nni, Kehinde Rapheal Oluseun to nileese 'Ralfabel' je atokun e,ni won gbe kale lati maa la awon eeyan loye lori awon igbese ti won le gbe, ti won yoo fi deni nla ohun lo ti di ayanfe gbogbo awon eeyan bayii, to fi je pe ki eto yii too bere ni won yo ti jokoo sidi radio won, afigba to ba pari ki won too dide se ohunkohun ti won ba fee se. Ohun tawon eeyan ri niyen, ti won n pariwo kiri bayii pe 'Eto Akaso Igbega ma ti daraba ni Radio Lagos'.
Fun ipolowo oja tabi ohunkohun ti e ba fee mo nipa eto yii, e pe Ogbeni Oluseun sori nomba yii
No comments:
Post a Comment