IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 21 February 2018

E wo Segun Akinjagunla,okan ninu awon omo orile-ede yii, to n fi orin gbe ilu re ga loke-okun

Okan ninu awon omo orile-ede yii ti won febun t'Olorun fun won gbe oruko orile-ede yii ga loke-okun lOgbeni Segun Akinjagunla tawon ololufe e mo si Oluomo. Ise orin emi kiko lokunrin naa yan laayo, o to ojo meta to ti wa lenu e, bee lo ti gbe opolopo rekoodu jade.

Gbogbo awon eeyan to mo okunrin yii daadaa ni won so pe olopolo pipe to n lo ebun tOlorun fun un  gbe ogo orile-ede yii ga niluu London to n gbe ni.

Enikeni to ba ri Segun, omo Akinjagunla, e so fun un pe Ojutole se sadankaata fun un bo se je omo Yoruba atata laarin awon oyinbo alawo funfun.
 

No comments:

Post a Comment

Adbox