IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 21 February 2018

Awon omo Saheed Osupa, Suliyat ati Akeem n jaye ori won l'Amerika

Omo ki i pe e dagba o, Akeem Okunola, akobi gbajumo akorin fuji nni, King Saheed Osupa ati aburo e, Suliyat le n wo yii o. Orile-ede Amerika lawon mejeeji wa, ti won ti n jaye ori ara won.

K'Olorun ma pa pomo folomo, kawon to n  woju Olorun naa romo alalubarika gbejo.

No comments:

Post a Comment

Adbox