IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Monday, 26 February 2018

Awon olorin Islam dara nibi ayeye ikomo Obi Rere

Ojo nla tawon olorin islam ko ni i gbagbe boro lojo  Abameta, Satide, to koja yii, ojo naa ni okan ninu won, Alaaja Aminat Ajao Abubakar tawon eeyan mo si  Obi Rere atoko e ko omo won jade.  tuntun jade.

Boya ni olorin islam kan wa ti ko si nibi ayeye ikomo naa to waye niluu Ilorin, gbogbo won pata ni won lu ibe pa. Gbajugbaja akorin fuji nni, Saheed Osupa lolorin ti won pe fun ayeye naa, bee lawon akorin islam mi-in naa korin lojo yii.

Die ninu awon foto ti Ojutole mu wa fun yin lojo naa niyii.












   

1 comment:

Adbox