IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Monday, 26 February 2018

Bukola Fagbuyi ree o, Arewa osere tiata to gbafe

Okan ninu awon arewa osere tiata Yoruba, ti ewa re maa  n da awon okunrin lorun ni Bukola Fagbuyi tawon ololufe e mo si Bukky Apesin. Omo to dudu to n dan, to tun ga daadaa ni.

Opolopo fiimu ni Bukky ti kopa ninu e, bee lo ti gbe ere tie naa jade, lara awon fiimu osere yii to gbajumo daadaa ni 'Sekunola'. Odun to koja yii lo gbe eto ilera kan kale lati fi mu aye irorun ba awon agbalagba nidii ise naa. E je ka ki Bukola Apesin, arewa osere  tiata Yoruba to dangajia.
 

No comments:

Post a Comment

Adbox