IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 25 February 2018

Eyin Olomoge, e wa a gbo, Lateef Adedimeji, onitiata, ti niyawo o

Eyi ni lati so fun gbogbo eyin olomoge ti e n so pe e feran Abdulateef Oladimeji, gbogbo eyin orekelewa ti e so pe o wu yin ki osere naa je ade ori yin pe Lati ti lomobinrin to fee fe o.

Omobinrin daadaa ti osere to ga yin fee fi seyawo le n wo  pelu e yii, kawon ojuloge ti won ti ni i lokan pe Abdulateef yoo je ade ori awon tete wa ife ti won siwaju ooo.

No comments:

Post a Comment

Adbox