IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday, 27 January 2018

Toyosi Adesanya sayeye oku baba e ni Sagamu,gbogbo awon osere tiata ni won peju sibe










Bamubamu lawon osere tiata Yoruba pe sibi ti okan lara won,Toyosi Adesanya Ileyemi, ti sayeye oku baba e, Alaaji Muhammed Basir Adesanya tawon eeyan mo si Ibe  to ku lose to koja, leni aadorin odun.
Eto ale awon osere ti won n pe ni 'Artiste Night'  ni won koko se lojo Aje, Monde to koja yii, nibi tawon osere ti seye nla fun baba okan ninu won yii. Orisirisi eto alarinrin ni won se nibi eto yii to waye nitosi aafin Oba Ewusu ni Makun, Sagamu, ipinle Ogun. 

Ojo Isegun,Tuesde ni won seto adura ojo mejo ti won maa n se fun oku musulumi fun baba yii, ojo naa lawon osere gbogbo waa fikale ye okan ninu won si. Leesi funfun lawon omo oku pelu awon oko won wo lojo naa,bee lawon ore oku ti won jo n se wole-wode nigba aye e naa wo aso kan naa.

Ohun to foju han lojo yii ni pe aye ye Alaaji Basir, o si daju pe orun yoo dara fun ju bee lo.   

No comments:

Post a Comment

Adbox