Inu ayo ati idunnu nla ni ilu mo on ka osere fuji nni, Alaaji Sulaimon Adio Atawewe wa bayii, akobi e to wa lorile-ede Amerikaniyawo e bimo.
Latigba tiroyin ayo yii ti sele lawon eeyan ti n ki osere nla tawon eeyan tun mo si Etu Fuji ku oriire oore ayo nla ohun
No comments:
Post a Comment