
Gbara ti aworan ibi ti Mercy ati omokunrin naa ti n jete ara won gori afefe lawon eeyan ti n binu foro ti ko dara ranse si i. Ohun ti won so ni pe ki i se iru e to je abiyamo ati iyaale ile lo ye ki okunrin olokunrin maa lo mo beeyen,ti iyen tun fenu ko o lenu.
Se lawon eeyan ti n won binu so pe nitori ki Mercy le raaye iranu lo se fi oko e sile. Sugbon ohun tawon to feran obinrin naa so ni pe ko si ohun to buru ninu ohun to se yii,nitori pe idi ise eni,leeyan ti n moni lole. Ju gbogbo e lo,awon eeyan n binu si Mercy gidigidi.
No comments:
Post a Comment