Gbogbo awon ebi, ara,ore ati ojulumo ni won peju-pese ba Mama Kudirat Anifowose sayeye ojoobi ogota odun ati ayeye ifeyinti lenu ise oba.



Ile mama naa to wa ni Itele, nipinle Ogun lawon eeyan ti loo ba sayeye nla ohun. Adura pataki fun iya olojoobi ni won koko bere eto yii,ko too di pe jije ati mimu waye ni pereu. Gbajumo sorosoro ori redio, Bento Salami lo dari ayeye naa.
Iroyin Ojutole-Toko ba mama dupe lowo Olorun pe won le odun kan si i loke eepe.
No comments:
Post a Comment