IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday, 30 January 2018

AKIN OLAIYA OSERE TIATA YORUBA ATAWON EBI E REE O

Okan pataki ninu awon gbajumo osere tiata Yoruba ni Akin Olaiya,osere naa ki i se majesin ninu awon  onitiata ile wa. Laipe yii lo gbe  foto awon omo atiyawo e sori ero ayelujara.Eyin naa, e foju lounje.

No comments:

Post a Comment

Adbox