IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday, 30 January 2018

O MA SE O,MAMA OLAMIDE BADOO TI KU O

Iroyin to te wa lowo bayii ni pe gbajumo olorin takasufee nni,Olamide Badoo ti padanu mama e. Funra osere nla tawon eeyan feran daadaa ti won n tun n ni Badoo lo gbe e sori ero ayelujara pe maam oun ti ku.
Gbara tiroyin aburu yii kan awon osere egbe e lara ni won ti n ba a kedun ajalu to sele si i yii.
E o ranti pe ko ti i to odun meji ti Olamide padanu baba e.

No comments:

Post a Comment

Adbox