IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday, 26 January 2018

IROYIN OJUTOLE KI OGA-AGBA EKA KARA-KATA NILEESE RADIO LAGOS-EKO FM, ALAAJI KAYODE ADUMADEYIN KU ORIIRE AYEYE OJOOBI WON

Gbogbo awa osise nileese magasinni 'Iroyin Ojutole' ki oga-agba leka kara-kata nileese Radio Lagos ati Eko Fm, Alaaji Kayode Adumadeyin ku oriire ayeye ojoobi won to waye lonii.

A gba a ladura fun won pe ki won se opo odun laye, ki igbega nla nla tunbo maa ba won, ki Olorun yonda gbogbo ohun ti won n fe fun won nirorun. Hapi Batide sa, igba odun,iseju aaya ni fun Alaaji Kay ti wa.

No comments:

Post a Comment

Adbox