Okan
ninu awon omo orile-ede yii tI won se daadaa ninu awon akorin emi niluu
Ivory Coast lohun-un ni Ajiyinrere Ilesanmi Olamoju, opo rekoodu
lokunrin naa ti gbe jade.
Bayii ilu mo on ka akorin emi yii sese pari ise lori rekoodu e tuntun tope akole re ni 'Gborimisoke'.Awo naa tileese Ola Salam record gbe jade lawon omoleyin Jesu fi n gbadun ara wo lasiko yii. Opo orin emi gidi ti eni ti o n le ile ologoje logun lo kun inu rekoodu naa fofo.Gbogbo ibi ti won ti n ta ojulowo rekoodu lawon eeyan yoo ti ri rekoodu tuntun yii ra.

No comments:
Post a Comment