IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Thursday, 25 January 2018

Haaaa, olugbanimoran pataki fun gomina Ambode tele lori oro ere idaraya, Deji Tinubu ti ku o

Taofik Afolabi
Iroyin ajalu to te wa lowo bayii ni pe olugbanimoran pataki lori ere oro idaraya nigba kan fun gomina ipinle Eko,Ogbeni Akinwumi Ambode, iyen Deji Tinubu, ti ku o.

Gege bi a se gbo, nibi ti okunrin naa ti n gba boolu losan ojo Ojobo, anaa lo ti subu lule lojiji, ti won gbe e digbadigba lo sile iwosan,sugbon irole ojo naa lo ku.
Ki Olorun fori ji i,ko si ro awon ebi loju.

No comments:

Post a Comment

Adbox