Gbogbo awa osise ileese Ojutole Blog la ki gbajumo olorin islam nni, Alaaja Mufuliat Mojere, ku oriire ayeye ojoobi e to waye lonii. Adura wa fun omo Imaamu ni pe ko se opolopo odun laye ninu ola,ola, alaafia ara ati ohun meremere. Igba odun,odun kan ni fun Mojere ti wa.
No comments:
Post a Comment