IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 28 January 2018

Se eyin mo pe ibeji ni Eniola Ajao, Kehinde re ree o

TaofikAfolabi

Pupo ninu awon ti won maa n wo fiimu agbelewo ni won ko mo pe ibeji ni gbajumo osere tiata Yoruba nni,Eniola Ajao, awon to mo pe ibeji losere naa ko po rara.

Ojo ayeye ojoobi e to waye lose to koja lohun-un larewa osere yii safihan Kehinde yii fun gbogbo awon eeyan ti won wa nibi ayeye ojoobi won ohun. Kehinde,Eniola Ajao ree o


 

No comments:

Post a Comment

Adbox