IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 31 January 2018

E je ka ba Temidayo Ekson,osere tiata Yoruba to gbamuse yo ayo ojoobi e

Gbogbo awa osise ileese Iroyin Ojutole pata la ba gbajumo osere tiata Yoruba nni,Temidayo Ekson Debby dupe lowo Olorun fun ayajo ojoobi e. A ba a yo pe o le odun kan si i laye, a sadura fun o pe ki o se opolopo odun laye ninu ola, ola,alaafia ati oriire nla

Hapi Batide Temidayo ti wa.

No comments:

Post a Comment

Adbox