![]() | ||
Destiny |
Ile igbafe to wa leti okun ti won n pe ni 'Alpha Beach' to wa ni l'Ekki ni yoo ti waye laago mejila osan. Awon odomode olorin takasufee ti won n je Daliment ati Destiny tawon eeyan tun mo si KGN Boys naa yo forin dabira nibi ere ita gbangba naa.
Lasiko to n ba wa soro, oga agba ileese KGN, Ogbeni Kayode Jinaid, so pe ojo naa lawon eeyan yoo tun lanfaani lati gbadun orin aladun ati ijo gidi lati
enu awon odomode olorin ti won n pe ni KGN Boys.
No comments:
Post a Comment