IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 28 January 2018

Oni lojo ibi Obesere, a ki Ologbojo ku oriire

Gbogbo awa osise ileese Iroyin Ojutole la ki gbajumo ati ilu mo  on ka osere fuji nni,Alaaji Abass Akande Obesere fun tayeye ojoobi e to n se lonii.
Adura wa ni pe ki Paramount King of Fuji sopo odun laye ninu ola, arisiki ati alaaafia ara.

Igba odun, iseju aaya ni fun Vice-Chancellor gbogbo awon onifuji pata.

No comments:

Post a Comment

Adbox