Iroyin to te wa lowo bayii ni pe Arabinrin Ajiboye, mama to bi manija Pasuma, iyen Mattew Ajiboye tawon eeyan mo si Ididowo ti ku. Aaro ana la gbo pe mama naa jade laye leni odun mejidinlogorun-un. Latigba tisele yii sele lawon eeyan ti n ranse ibanikedun si okunrin naa. Gbara tisele yii waye ni Ididowo tin fi leta ranse sawon eeyan ti won sunmo on pe mama oun ti ku. A ba Ididowo kedun iku mama e yii, Olorun yoo te won safefe ire.Sun ree o,iya Mathew
No comments:
Post a Comment