EGBE BEBE AANU FUN ORIYOMI HAMZAT IROYIN OJUTOLE January 11, 2025 Awon Omo egbe alatileyin fun gbajugbaja gbaja sorosoro ori radio nni, Alhaji ORIYOMI Hamzat lati orile ede America ati Canada t... KAA SIWAJU
Saheed Arẹgbẹsọla la n fẹ nipo ọba Isọlọ-Oloye Taorid Farounbi Alado IROYIN OJUTOLE January 10, 2025 Olori ẹbi Papa Alagbẹji, niluu Isọlọ, nipinlẹ Eko, Oloye Taorid Farounbi ti gbogbo aye mọ si Alado ti rọ gomina ipinlẹ Eko, Ọgbẹ... KAA SIWAJU
GBAJUGBAJA ONiROYIN, OLAIDE GOLD DI IYA IROYIN ILU MEIRAN, NIPINLE EKO IROYIN OJUTOLE January 07, 2025 Olaide Aderonke Gold ti gbogbo Ololufe e mo si Olaide Gold di IYA IROYIN fun ilu Meiran ni tile toko ati agbegbe e. Yiniyini ki ... KAA SIWAJU
Prophecy for 2025: A Year of Vengeance, Harvest, and Divine Shifts By Pro. Kingsley Aitafo IROYIN OJUTOLE December 21, 2024 Prophet Kingsley Aitafo, under the grace and spiritual leadership of His Eminence Rev. Pastor Samuel Belehou Oshoffa, founder of... KAA SIWAJU
Ijọ Cherubim ati Seraphim Society pe Ọgọrun-un ọdun. bẹẹni wọn ṣe iranti iku oludasilẹ ijọ wọn to papoda lọgbọn ọdun sẹyin IROYIN OJUTOLE December 21, 2024 KAA SIWAJU
Ojiṣẹ lṣẹdalẹ ṣatupalẹ ewi Wọle Ṣoyinka, Abiku si ede Yoruba. IROYIN OJUTOLE October 14, 2024 Ọgbẹni Olubunmi Olukanni, tawọn kan tun pe ni Ojiṣẹ Iṣẹdalẹ, to fi orileede Amerika, ni California, ti tun ewi kan ti Ọjọgbọn Wọ... KAA SIWAJU
Iwode:Oloye Rafiu Okanlawon Oseni sepade pelu awon olugbe agbegbe re IROYIN OJUTOLE July 30, 2024 Oodu ni Oloye Rafiu Okanlawon Oseni eni ti opo eeyan mo si Elele je, okunrin naa ni Oloye apagunpote ilu Igbein ki i saimo... KAA SIWAJU
Àtúntò òdodo nìkan ni ọ̀nà àbáyọ kan ṣoṣo sí ìṣoro orílè-èdè yìí-Wòlíì Wálé Ọlágúnjú IROYIN OJUTOLE June 30, 2024 Taofik Afọlabi Gbajugbaja wolii agbaaye nni, to tun jẹ oludasilẹ ajọ kan to n pe fun atunto orileede yii, iyẹn, ‘Directorate o... KAA SIWAJU
Ope o: Omo Ayangbajumo, bi Ibeji l'Amerika IROYIN OJUTOLE June 14, 2024 Inu ayo ati idunnu nla ni gbajumo obinrin onllu nni, Queen Eniola Abiọdun Lias ti gbogbo aye mo si Queen... KAA SIWAJU
'Ṣọọṣi Olukọya kọ lo ju Fẹmi Jimoh sẹwọn ọdun mẹsan-an, ko rẹni gba beeli rẹ ni" IROYIN OJUTOLE June 08, 2024 Ileejọsin Mountain of Fire and Miracles Ministries (MFM) ti ṣapejuwe ọrọ ti ọkan ninu awọn Pasitọ ṣọọṣi naa tẹlẹ sọ ninu fọnran ... KAA SIWAJU
Olu tilu Itori, Oba Fatai Akamo salaye Idi ti to fi bẹrẹ niwaju Gomina Dapọ Abiọdun IROYIN OJUTOLE May 31, 2024 Olu tiluu Itori, Ọba Abdulfatai Akamọ, ti ṣalaye idi to fi kunlẹ ṣiwaju Gomina Dapọ Abiọdun, tipinlẹ Ogun lakooko ti wọn jọ fọrọ... KAA SIWAJU
Awon ebi sadura odun kerinla fun Alhaji Rasheed Adio Adeyinka Second Barrister lAgerige IROYIN OJUTOLE May 10, 2024 Pitimu lawon ebi, ara, atawon ojulumo pejupese sadura odun kerinla to jade laye fun gbajumo olorin Fuji nni, Alhaji Rasheed Adio... KAA SIWAJU
Wọn fẹẹ maa fọrọ epo pẹntiroolu sọ ijọba lẹnu ni- Ṣẹgun Ṣowumi. IROYIN OJUTOLE May 10, 2024 Ọtunba Ṣẹgun Ṣowunmi, oludije fun ipo gomina labẹ ẹgbẹ oṣelu PDP, ti sọ pe awọn kan lo wa lati maa fi ọrọ epo pẹntiroolu sọ ijọb... KAA SIWAJU