IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday 30 July 2024

Iwode:Oloye Rafiu Okanlawon Oseni sepade pelu awon olugbe agbegbe re

 
 

Oodu ni Oloye Rafiu Okanlawon Oseni eni ti opo eeyan mo si Elele je, okunrin naa ni Oloye  apagunpote ilu Igbein ki i  saimo fun gbogbo olugbe ipinle re.
Oloye to gbajumo yii ti wa sepade pelu awon olugbe agbegbe Mowe,Ofada ati awon ilu mi- in to yi won ka loni ojo Tusidee to si ti je ko di mimo pe,ki won se jeeje lasiko iwode ati ifehonuhan ti yoo waye lose yii

Oloye Elele ninu oro re lo ti so pe, Aare Bola Tinubu ni erongba rere lokan fun gbogbo olugbe ati omo bibi orileede ede yii, sugbon omi lo si po ju oka lo fun Aare wa.

Apagunpote ilu Igbein niluu Abeokuta ipinle Ogun ti waa so pe,kawon eeyan oun ma se lowo ninu ija lasiko iwode ki alaafia le joba,o wa be olori fawon Hausa agbegbe re pe,ife nikan lo le mu ilu tesiwaju .

No comments:

Post a Comment

Adbox